Arawọn

Lyrics: Ojadua Emmanuel Temitope Music: Ojadua Emmanuel Temitope Hnnnn Cabasa bá mi jáwọn, Doctorflowz lóríi beat io Yurh Sometimes when I'm lone I go deep in thought Kíni mò ń ronú kódé bí ò ń ṣe results Sundays to Thursday pẹ̀lú ọjọ́ Jimoh Carrying my cross all day mi ò báwọn díbọ́n Stepping into this game called hustle isn't funny Sometimes you go vulgar and think bitches only Bópẹ́ bóyá o, one day one day Ọ̀rọ̀ bíi ṣìná láyé mi Olúwa á gbé wọn dè Ṣ'àdúrà kin ṣ'àmín kò sí ìjà ni churchi Èwo ni ìfojújọ́ ọmọ Ọlọ́run finújẹ́ onírọ́ òsì Wọn ò le sọ mí ṣókùnkùn torí mo ní torchi Nán le lérí pán l'óògùn, ẹgbẹ́ wọn ńní Porsche Nwa! Sọfún Uche kóbi Mba Pé èwo ni tìgara chicken níbi turkey wà? Pé èwo ló kan jet i pẹ̀lu títì ò da'a? Mehn I pray to fly high so k'Ọlọ́hun gbà
Arawọn ò yá ooo Àwọn jengbetiele Arawọn ò le Arawọn ò yá ooo Eh eehhhh eh Arawọn ò lé
Àwọn tí ò le fọṣọ wọn kómọ́ fẹ́ma brainwash wa Lóri p'ọ́nfẹ́ control wọ́nní káwọn pause wa Bojẹ́ tìjà nán báwá àwa gan ti bá force wá Àìfẹ́ ka gain wọn tánfẹ́ ṣírò loss wa If that shits don't stop mehnn I'll stop it Èwo ni kánma lérí léka whenn I was talking Orí tán lé tán ò le bá Ìka tán ní tán ò le kà Wọ́n le péjọ kán pégba but kán dẹ̀hìn lẹ́yìn flopping
Arawọn ò yá ooo Àwọn jengbetiele Arawọn ò le Arawọn ò yá ooo Eh eehhhh eh Arawọn ò lé
Sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ mi ló ń pèdè kí bad belly mérége Eh eh, kí bad belly mérége Sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ mi ló ń pèdè kí bad belly mérégé Kí bad belly mérége