By my side, by my side Jésù by my side I'm save in his arms, than any other place Jésù Jésù ni scope Ònà, òtító àti ìyè òhun ni code Follow who know road ko má lo fold Make e no cum be like say you untold Óyá decode Na your real antidote no be procold In him we live, we move, and have our Being, He made everything comes to Being Ta lònà, Jésù Ìyè ńkó, Jésù Na em be the road safety wey dey this road, no go lost, follow who no road No "gok" am, Tèlé who know road
Jésù Jésù Jésù Na em be the way Every other way no be way, mó lo fi ara wé Málo fi ìgbàgbó re dóla sho gbó mi Alayé
My jésù my jésù Your love dey draw me like pencil Mo gbó pé e fi five loaves of bread Pèlú two fish bó five thousand ah ah E no get mountain he cannot move He's more than enough A thousand times enough He loved me first Before I fall I love Wóò okùn èmí mi ni Jésù Life wire tí ò ní cable Tóso mí pò mó àwon ángélì Jagunjagun èyan máíkéélì Óní kí n receive bí ti Adébóyè kí n redeem Ki ń máa jó bíi enenche kí n fòfáyò mi nsé elésè
Jésù Jésù Jésù Na em be the way Every other way no be way, mó lo fi ara wé Málo fi ìgbàgbó re dóla sho gbó mi Alayé
Ohun gbogbo ló lè Se Jésù alèwélère Baba aláwo yen ma gba owó,gba adìre, ótú ma fall hand e, "Òóbì" Ohun gbogbo ló lè Se Jésù alèwélère Baba aláwo yen ma gba owó,gba adìre, ótú ma fall hand e, "Òóbì"